Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Water: (Its weakness,) of faintness and cowardice

2 ẹsẹ · 84 abala

Àwọn ẹsẹ nípa (Its weakness,) of faintness and cowardice

  1. Àwọn ènìyàn Ai sì pa àwọn bí mẹ́rìndínlógójì nínú wọn. Wọ́n sì ń lépa àwọn ará Israẹli láti ibodè ìlú títí dé Ṣebarimu, wọ́n sì pa àwọn tí ń sọ̀kalẹ̀. Àyà àwọn ènìyàn náà sì já, ọkàn wọn sì pami.

  2. Gbogbo ọwọ́ yóò rọ, gbogbo orúnkún yóò di aláìlágbára bí omi.