Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Vision: Of the people, of the tongues of fire at Pentecost
Àwọn ẹsẹ nípa Of the people, of the tongues of fire at Pentecost
Lójijì ìró sì ti ọ̀run wá, gẹ́gẹ́ bí ìró ẹ̀fúùfù líle, ó sì kún gbogbo ilé níbi tí wọ́n gbé jókòó.
Ẹ̀là ahọ́n bí i iná sì yọ sí wọn, ó pín, ó sì bà lé olúkúlùkù wọn.