Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Vision: Of Elisha's servant, of the chariots of the Lord
Àwọn ẹsẹ nípa Of Elisha's servant, of the chariots of the Lord
Eliṣa sì gbàdúrà, “Olúwa, la ojú rẹ̀ kí ó ba à lè ríran.” Nígbà náà Olúwa la ojú ìránṣẹ́ náà, ó sì wò, ó sì rí òkè ńlá tí ó kún fún ẹṣin àti kẹ̀kẹ́ iná gbogbo yí Eliṣa ká.