Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Valleys: Often the scenes of idolatrous rites
Àwọn ẹsẹ nípa Often the scenes of idolatrous rites
Ẹ gbinájẹ fún ìṣekúṣe láàrín igi óákù àti lábẹ́ gbogbo igi tí ń gbilẹ̀; ẹ fi àwọn ọmọ yín rú ẹbọ nínú kòtò jíjìn àti lábẹ́ àwọn pàlàpálá òkúta.