Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Valleys: Rough valleys, when uncultivated and barren
Àwọn ẹsẹ nípa Rough valleys, when uncultivated and barren
kí àwọn àgbàgbà ìlú náà kí wọn mú ẹgbọrọ abo màlúù náà sọ̀kalẹ̀ wá sí àfonífojì tí ó ní omi ṣíṣàn kan, tí a kò ro, tí a kò sì gbìn, kí wọn kí ó sì ṣẹ́ ọrùn ẹgbọrọ màlúù náà níbẹ̀ ní àfonífojì náà.