Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Valleys: Of Israel well tilled and fruitful

2 ẹsẹ · 58 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Of Israel well tilled and fruitful

  1. Nísinsin yìí, àwọn ará Beti-Ṣemeṣi ń kórè jéró wọn ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, nígbà tí wọ́n wo òkè tí wọ́n sì rí àpótí ẹ̀rí Olúwa, wọ́n yọ̀ níwájú rẹ̀.

  2. Agbo ẹran ni a fi wọ pápá tútù náà ní aṣọ; àfonífojì ni a fi ọkà bò mọ́lẹ̀, wọ́n hó fún ayọ̀, wọ́n ń kọrin pẹ̀lú.