Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Valleys: Ditches in, filled with water

2 ẹsẹ · 58 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Ditches in, filled with water

  1. Ó sì wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa sọ, ‘Jẹ́ kí àfonífojì kún fún ọ̀gbun.’

  2. Nítorí èyí ni Olúwa wí, o kò ní í rí afẹ́fẹ́ tàbí òjò, bẹ́ẹ̀ ni àfonífojì yìí yóò kún pẹ̀lú omi, àti ìwọ àti ẹran ọ̀sìn àti pẹ̀lú àwọn ẹran yóò mu.