Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tyre: Soldiers of, supplied by Persia, &c

2 ẹsẹ · 47 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Soldiers of, supplied by Persia, &c

  1. “ ‘Àwọn ènìyàn Persia, Ludi àti Puti wà nínú jagunjagun rẹ àwọn ẹgbẹ́ ọmọ-ogun rẹ. Wọ́n gbé asà àti àṣíborí wọn ró sára ògiri rẹ, wọn fi ẹwà rẹ hàn.

  2. Àwọn ènìyàn Arfadi àti Heleki wà lórí odi rẹ yíká; àti àwọn akọni Gamadi, wà nínú ilé ìṣọ́ rẹ. Wọ́n fi àwọn asà wọn kọ ara odi rẹ; wọn ti mú ẹwà rẹ pé.