Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tyre: Envy against the Jews a cause of its destruction
Àwọn ẹsẹ nípa Envy against the Jews a cause of its destruction
“Ọmọ ènìyàn, nítorí pé Tire sọ nípa Jerusalẹmu pé, ‘Háà! A fọ́ èyí tí í ṣe bodè àwọn orílẹ̀-èdè, a yí i padà sí mi, èmi yóò di kíkún, òun yóò sì di ahoro,’