Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Wicked: Enemies of all righteousness
Àwọn ẹsẹ nípa Enemies of all righteousness
“Ìwọ ti ó kún fún àrékérekè gbogbo, àti fún ìwà ìkà gbogbo, ìwọ ọmọ èṣù, ìwọ ọ̀tá ohun gbogbo, ìwọ kì yóò ha dẹ́kun láti máa yí ọ̀nà òtítọ́ Olúwa po?