Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Wicked: Children of disobedience

2 ẹsẹ · 68 abala

Wá "Titles and Names of the Wicked"

Àwọn ẹsẹ nípa Children of disobedience

  1. nínú èyí tí ẹ̀yin ti gbé rí, àní bí ìlànà ti ayé yìí, gẹ́gẹ́ bí aláṣẹ agbára ojú ọ̀run, ẹ̀mí tí n ṣiṣẹ́ ni ìsinsin yìí nínú àwọn ọmọ aláìgbọ́ràn.

  2. Lórí àwọn wọ̀nyí ni ìbínú Ọlọ́run ń bọ̀ wá.