Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Wicked: Wicked doers

2 ẹsẹ · 68 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Wicked doers

  1. Ní ojoojúmọ́ ní èmi yóò wá máa pa a lẹ́nu mọ gbogbo àwọn ènìyàn búburú ilẹ̀ náà; èmi yóò gé àwọn olùṣe búburú kúrò ní ìlú Olúwa.

  2. Ènìyàn búburú ń tẹ́tí sí ètè tí ń sọ ibi; òpùrọ́ a máa fetí sí ahọ́n búburú.