Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Wicked: Children in whom is no faith
Àwọn ẹsẹ nípa Children in whom is no faith
Ó sì wí pé, “Èmi yóò pa ojú mi mọ́ kúrò lára wọn, èmi yóò sì wò ó bí ìgbẹ̀yìn in wọn yóò ti rí; nítorí wọ́n jẹ́ ìran alágídí, àwọn ọmọ tí kò sí ìgbàgbọ́ nínú wọn.