Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Wicked: Adversaries of the Lord
Àwọn ẹsẹ nípa Adversaries of the Lord
A ó fọ́ àwọn ọ̀tá Olúwa túútúú; láti ọ̀run wá ni yóò sán àrá sí wọn; Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ òpin ayé. “Yóò fi agbára fún ọba rẹ̀, yóò si gbé ìwo ẹni àmì òróró rẹ̀ sókè.”