Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Church: Temple of God

2 ẹsẹ · 45 abala

Wá "Titles and Names of the Church"

Àwọn ẹsẹ nípa Temple of God

  1. Ṣé ẹ̀yin kò tilẹ̀ mọ̀ pé tẹmpili Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́? Àti pẹ̀lú pe Ẹ̀mí Ọlọ́run ń gbé inú yín?

  2. Bí ẹnikẹ́ni bá ba tẹmpili Ọlọ́run jẹ́, òun ni Ọlọ́run yóò parun; nítorí pé mímọ́ ni tẹmpili Ọlọ́run, èyí tí ẹ̀yin jẹ́.