Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Church: Flock of God

2 ẹsẹ · 45 abala

Wá "Titles and Names of the Church"

Àwọn ẹsẹ nípa Flock of God

  1. Èmi fúnra mi yóò darí àgùntàn mi, èmi yóò mú wọn dùbúlẹ̀, ni Olúwa Olódùmarè wí.

  2. Ẹ máa tọ́jú agbo Ọlọ́run tí ń bẹ láàrín yín, ẹ máa bojútó o, kì í ṣe àfipáṣe, bí kò ṣe tìfẹ́tìfẹ́; kó má sì jẹ́ fún èrè ìjẹkújẹ, bí kò ṣe pẹ̀lú ìpinnu tí ó múra tan.