Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Church: Holy mountain

1 ẹsẹ · 45 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Holy mountain

  1. Báyìí ni Olúwa wí, “Mo yípadà sí Sioni èmi ó sì gbé àárín Jerusalẹmu. Nígbà náà ni a ó sì pé Jerusalẹmu ni ìlú ńlá òtítọ́; àti òkè ńlá Olúwa àwọn ọmọ-ogun, ni a ó pè ní òkè ńlá mímọ́.”