Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Church: Bride of Christ
Àwọn ẹsẹ nípa Bride of Christ
Ọ̀kan nínú àwọn angẹli méje, tí wọ́n ni ago méje, tí ó kún fún ìyọnu méje ìkẹyìn sì wá, ó sì ba mi sọ̀rọ̀ wí pé, “Wá níhìn-ín, èmi ó fi ìyàwó, aya Ọ̀dọ́-àgùntàn hàn ọ́.”