Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Titles and Names of the Church: House of God
Àwọn ẹsẹ nípa House of God
Ṣùgbọ́n bí mo bá pẹ́, kí ìwọ lè mọ̀ bí ó ti yẹ fún àwọn ènìyàn láti máa hùwà nínú ilé Ọlọ́run, tì í ṣe ìjọ Ọlọ́run alààyè, ọ̀wọ́n àti ìpìlẹ̀ òtítọ́.
àti bí a ti ni àlùfáà gíga lórí ilé Ọlọ́run;