Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Vine: Eshcol

2 ẹsẹ · 42 abala

Wá "The Vine"

Àwọn ẹsẹ nípa Eshcol

  1. Nígbà tí wọ́n dé àfonífojì Eṣkolu, wọ́n gé ẹ̀ka kan tó ní ìdì èso àjàrà gireepu kan. Àwọn méjì sì fi ọ̀pá kan gbé e; wọ́n tún mú èso pomegiranate àti èso ọ̀pọ̀tọ́ pẹ̀lú.

  2. Wọ́n sì sọ ibẹ̀ ní àfonífojì Eṣkolu nítorí ìdì èso gireepu tí àwọn ọmọ Israẹli gé níbẹ̀.