Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Vine: Of Christ
Àwọn ẹsẹ nípa Of Christ
“Èmi ni àjàrà tòótọ́, Baba mi sì ni olùṣọ́gbà.
Gbogbo ẹ̀ka nínú mi tí kò bá so èso, òun a mú kúrò, gbogbo ẹ̀ka tí ó bá sì so èso, òun a wẹ̀ ẹ́ mọ́, kí ó lè so èso sí i.