Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Vine: Frequently injured by hail and frost
Àwọn ẹsẹ nípa Frequently injured by hail and frost
Ó fi yìnyín ba àjàrà wọn jẹ́ ó bá èso sikamore wọn jẹ́.
Ó sọ òjò di yìnyín, àti ọ̀wọ́-iná ní ilẹ̀ wọn;
Ó lu àjàrà wọn àti igi ọ̀pọ̀tọ́ wọn ó sì dá igi orílẹ̀-èdè wọn.