Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Stars: False gods frequently worshipped under the representation of

2 ẹsẹ · 40 abala

Àwọn ẹsẹ nípa False gods frequently worshipped under the representation of

  1. Ẹ̀yin ti gbé ibi ìrúbọ àwọn ọba yín sókè, ibùgbé àwọn òrìṣà yín, àní, ti àwọn òrìṣà yín tí ó níyì jùlọ, èyí tí ẹ̀yin fi ọwọ́ ara yín ṣe.

  2. Ẹ̀yin sì tẹ́wọ́gbà àgọ́ Moleki, àti ìràwọ̀ Refani òrìṣà yín, àwòrán tí ẹ̀yin ṣe láti máa bọ wọ́n. Nítorí náà èmi yóò kó yín lọ sí ìgbèkùn rékọjá Babeli.’