Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Punishment of the Wicked: Everlasting burnings
Àwọn ẹsẹ nípa Everlasting burnings
Ẹ̀rù ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní Sioni; ìwárìrì bá àwọn tí kò gba Ọlọ́run gbọ́: “Ta ni nínú wa lólè gbé pẹ̀lú iná ajónirun? Ta ni nínú wa lólè gbé pẹ̀lú iná àìnípẹ̀kun?”