Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Punishment of the Wicked: Noisome beasts
Àwọn ẹsẹ nípa Noisome beasts
Èmi yóò rán àwọn ẹranko búburú sí àárín yín, wọn yóò sì pa àwọn ọmọ yín, wọn yóò run agbo ẹran yín, díẹ̀ nínú yín ni wọn yóò ṣẹ́kù kí àwọn ọ̀nà yín lè di ahoro.