Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Punishment of the Wicked: Bringing down their pride
Àwọn ẹsẹ nípa Bringing down their pride
Èmi yóò jẹ ayé ní ìyà nítorí ibi rẹ̀, àwọn ìkà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Èmi yóò fi òpin sí gààrù àwọn agbéraga èmi ó sì rẹ ìgbéraga àwọn aláìláàánú sílẹ̀.