Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Providence of God: The special preservation of saints

3 ẹsẹ · 41 abala

Wá "The Providence of God"

Àwọn ẹsẹ nípa The special preservation of saints

  1. Nítorí pé Olúwa fẹ́ràn ìdájọ́ òtítọ́, kò sì kọ àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ sílẹ̀. Àwọn olódodo ni a ó pamọ́ títí ayérayé, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ ènìyàn búburú ni a ó ké kúrò.

  2. Nítorí yóò fi àṣẹ fún àwọn angẹli nípa tìrẹ láti pa ọ́ mọ́ ní gbogbo ọ̀nà rẹ;

  3. Àti pé gbogbo irun orí yín ni a ti kà pé.