Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Providence of God: Ordering the ways of men

3 ẹsẹ · 41 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Ordering the ways of men

  1. Ènìyàn a máa pète ọ̀nà ara rẹ̀ lọ́kàn an rẹ̀ ṣùgbọ́n Olúwa ní í pinnu ìgbésẹ̀ rẹ̀.

  2. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ète inú ọkàn ènìyàn, ṣùgbọ́n ìfẹ́ Olúwa ní ó máa ń borí.

  3. Olúwa ni ó ń ṣe olùdarí ìgbésẹ̀ ènìyàn. Báwo wá ni òye gbogbo ọ̀nà ènìyàn ṣe le yé ni?