Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Providence of God: Encourage themselves

1 ẹsẹ · 41 abala

Wá "The Providence of God"

Àwọn ẹsẹ nípa Encourage themselves

  1. Dafidi sì banújẹ́ gidigidi, nítorí pé àwọn ènìyàn náà sì ń sọ̀rọ̀ láti sọ ọ́ lókùúta, nítorí ti inú gbogbo àwọn ènìyàn náà sì bàjẹ́, olúkúlùkù ọkùnrin nítorí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, àti nítorí ọmọ rẹ̀ obìnrin ṣùgbọ́n Dafidi mú ara rẹ̀ lọ́kàn le nínú Olúwa Ọlọ́run rẹ̀.