Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Strife: Wrath

2 ẹsẹ · 57 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Wrath

  1. Ènìyàn onínú ríru dá ìjà sílẹ̀ ṣùgbọ́n onísùúrù paná ìjà.

  2. Nítorí bí fífún omi ọmú tí í mú wàrà wá, tí fífún imú sì ń mú ẹ̀jẹ̀ jáde, bẹ́ẹ̀ ni rírú ìbínú sókè í mú ìjà wá.”