Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Strife: Hypocrites make religion a pretence for
Àwọn ẹsẹ nípa Hypocrites make religion a pretence for
Àwẹ̀ yín sì parí nínú ìjà àti asọ̀, àti lílu ọmọnìkejì ẹni pa pẹ̀lú ìkùùkuu. Ẹ̀yin kò le è gbààwẹ̀ bí ẹ ti ń ṣe lónìí kí ẹ sì retí kí a gbọ́ ohùn un yín ní ibi gíga.