Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Strife: Forbidden

2 ẹsẹ · 57 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Forbidden

  1. Má ṣe fẹ̀sùn kan ènìyàn láìnídìí, nígbà tí kò ṣe ọ́ ní ibi kankan rárá.

  2. Ohun tí o ti fi ojú ara rẹ rí má ṣe kánjú gbé e lọ sílé ẹjọ́ nítorí kí ni ìwọ yóò ṣe ní ìgbẹ̀yìn bí aládùúgbò rẹ bá dójútì ọ́?