Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Strife: Pride

2 ẹsẹ · 57 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Pride

  1. Ìgbéraga máa ń dá ìjà sílẹ̀ ni ṣùgbọ́n ọgbọ́n wà nínú àwọn tí ń gba ìmọ̀ràn.

  2. Ọ̀kánjúwà ènìyàn a máa dá ìjà sílẹ̀, ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé Olúwa yóò gbilẹ̀.