Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Denial: Ministers especially called to exercise

2 ẹsẹ · 41 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Ministers especially called to exercise

  1. Ṣùgbọ́n dípò bẹ́ẹ̀, ni ọnà gbogbo, àwa ń fi ara wa hàn bí àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sùúrù, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú wàhálà,

  2. nípa nínà, nínú túbú, nínú ìrúkèrúdò, nínú iṣẹ́ àṣekára, nínú àìsàn, nínú ìgbààwẹ̀.