Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Denial: Being crucified to the world
Àwọn ẹsẹ nípa Being crucified to the world
Ṣùgbọ́n kí a má ṣe rí i pé èmi ń ṣògo, bí kò ṣe nínú àgbélébùú Jesu Kristi Olúwa wa, nípasẹ̀ ẹni tí a ti kan ayé mọ́ àgbélébùú fún mi, àti èmi fún ayé.