Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Denial: Denying ungodliness and worldly lusts

2 ẹsẹ · 41 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Denying ungodliness and worldly lusts

  1. Nítorí náà kí ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ jẹ ọba lórí ara kíkú yín kí ó lè ba à máa ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀.

  2. Ó ń kọ́ wa láti sẹ́ àìwà-bí-Ọlọ́run àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ayé, kí a sì máa wà ní àìrékọjá, ní òdodo àti ní ìwà-bí-Ọlọ́run ní ayé ìsinsin yìí,