Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Revenge: Trust in God

2 ẹsẹ · 32 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Trust in God

  1. Má ṣe wí pé, “N ó sẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ.” Dúró de Olúwa yóò sì gbà ọ́ là.

  2. Ẹ máa wà ní inú kan náà sí ara yín. Ẹ má ṣe gbéraga, ṣùgbọ́n ẹ má tẹ̀lé àwọn onírẹ̀lẹ̀. Ẹ má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n ní ojú ara yín.