Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Revenge: Be thankful for being kept from taking

2 ẹsẹ · 32 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Be thankful for being kept from taking

  1. Dafidi sì wí fún Abigaili pé, “Alábùkún fún ni Olúwa Ọlọ́run Israẹli, tí ó rán ọ lónìí yìí láti pàdé mi.

  2. Ìbùkún ni fún ọgbọ́n rẹ, alábùkún sì ni ìwọ, tí ó da mi dúró lónìí yìí láti wá ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀, àti láti fi ọwọ́ mi gba ẹ̀san fún ara mi.