Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Repentance: By the Apostles
Àwọn ẹsẹ nípa By the Apostles
Wọ́n jáde lọ láti wàásù ìrònúpìwàdà fún àwọn ènìyàn.
Tí mo ń sọ fún àwọn Júù, àti fún àwọn Giriki pẹ̀lú, ní ti ìrònúpìwàdà sí Ọlọ́run, àti ti ìgbàgbọ́ nínú Jesu Kristi Olúwa wa.