Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Repentance: Unavailing to Esau

2 ẹsẹ · 65 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Unavailing to Esau

  1. Kí o má bá à si àgbèrè kan tàbí aláìwà-bí-Ọlọ́run bi Esau, ẹni tí o tìtorí òkèlè oúnjẹ kan ta ogún ìbí rẹ̀.

  2. Nítorí ẹ̀yin mọ pé lẹ́yìn náà, nígbà tí ó fẹ́ láti jogún ìbùkún náà, a kọ̀ ọ́, nítorí kò ri ààyè ìrònúpìwàdà, bí o tilẹ̀ jẹ́ pé ó fi omijé wa a gidigidi.