Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Praise: The chorus when Solomon brought the ark into the temple

1 ẹsẹ · 106 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The chorus when Solomon brought the ark into the temple

  1. Àwọn afùnpè àti àwọn akọrin pa ohùn wọn pọ̀ sí ọ̀kan ṣoṣo, láti fi ìyìn àti ọpẹ́ fun Olúwa. Wọ́n fi ìpè, kimbali àti àwọn ohun èlò orin mìíràn mọ́ ọn, wọ́n gbé ohùn wọn sókè láti fi yin Olúwa, wọ́n ń kọrin pé, “Ó dára; ìfẹ́ rẹ̀ wà títí láéláé.” Nígbà náà ni ìkùùkuu ojú ọ̀run kún inú tẹmpili Olúwa,