Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Praise: Fulfilling of his promises

1 ẹsẹ · 106 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Fulfilling of his promises

  1. “Ìbùkún ni fún Olúwa tí ó ti fi ìsinmi fún Israẹli, ènìyàn rẹ̀ bí ó ti ṣèlérí. Kò sí ọ̀rọ̀ rẹ̀ kan tí ó kùnà nínú gbogbo ìlérí rere tí ó ti ṣe láti ọwọ́ Mose ìránṣẹ́ rẹ̀ wá.