Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Praise: Voice of melody

1 ẹsẹ · 106 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Voice of melody

  1. Dájúdájú, Olúwa yóò tu Sioni nínú yóò sì bojú àánú wo gbogbo ahoro rẹ̀; Òun yóò sọ gbogbo aṣálẹ̀ rẹ̀ di Edeni, àti aṣálẹ̀ rẹ̀ yóò rí bí ọgbà Olúwa. Ayọ̀ àti inú dídùn ni a ó rí nínú rẹ̀, ọpẹ́ àti ariwo orín kíkọ.