Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pilgrims and Strangers: Are strengthened by God

3 ẹsẹ · 35 abala

Wá "Pilgrims and Strangers"

Àwọn ẹsẹ nípa Are strengthened by God

  1. Bàtà rẹ̀ yóò jẹ́ irin àti idẹ, agbára rẹ̀ yóò sì rí bí ọjọ́ rẹ̀.

  2. Àwọn tí ń la àfonífojì omijé lọ wọn sọ ọ́ di kànga àkọ́rọ̀ òjò sì fi ìbùkún bò ó.

  3. Wọ́n ń lọ láti ipa dé ipá títí tí ọ̀kọ̀ọ̀kan fi farahàn níwájú Ọlọ́run ní Sioni.