Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Pilgrims and Strangers: Hate worldly fellowship
Àwọn ẹsẹ nípa Hate worldly fellowship
Ègbé ni fún mi tí èmi ṣe àtìpó ní Meṣeki, nítorí èmi gbé nínú àgọ́ ìlú Kedari!
Ó ti pẹ́ tí èmi ti ń gbé láàrín àwọn tí ó kórìíra àlàáfíà.