Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Parables: Pearl of great price
Àwọn ẹsẹ nípa Pearl of great price
“Bákan náà ni ìjọba ọ̀run dàbí oníṣòwò kan tí ó ń wá òkúta olówó iyebíye láti rà.
Nígbà tí ó rí ọ̀kan tí ó ni iye lórí, ó lọ láti ta gbogbo ohun ìní rẹ̀ láti le rà á.