Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Parables: Treasure hid in a field
Àwọn ẹsẹ nípa Treasure hid in a field
“Ìjọba ọ̀run sì dàbí ìṣúra kan tí a fi pamọ́ sínú oko. Nígbà tí ọkùnrin kan rí i ó tún fi í pamọ́. Nítorí ayọ̀ rẹ̀, ó ta gbogbo ohun ìní rẹ̀, ó ra oko náà.