Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Parables: Savour of salt

2 ẹsẹ · 74 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Savour of salt

  1. “Iyọ̀ dára: ṣùgbọ́n bí iyọ̀ bá di òbu, kín ni a ó fi mú un dùn?

  2. Kò yẹ fún ilẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò yẹ fún ààtàn; bí kò ṣe pé kí a kó o dànù. “Ẹni tí ó bá ní etí láti fi gbọ́ kí ó gbọ́.”