Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Offerings: Unacceptable, without gratitude
Àwọn ẹsẹ nípa Unacceptable, without gratitude
Èmi kí yóò bá ọ wí nítorí àwọn ìrúbọ rẹ, tàbí ọrẹ ẹbọ sísun rẹ, èyí tí ó wà níwájú mi ní ìgbà gbogbo.
“Rú ẹbọ ọpẹ́ sí Ọlọ́run, kí o sì san ẹ̀jẹ́ rẹ fún Ọ̀gá-ògo.