Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Offerings: All animal sacrifices must be eight days old or over
Àwọn ẹsẹ nípa All animal sacrifices must be eight days old or over
“Nígbà tí màlúù bá bímọ, tí àgùntàn bímọ, tí ewúrẹ́ sì bímọ, ọmọ náà gbọdọ̀ wà pẹ̀lú ìyá rẹ̀ fún ọjọ́ méje. Láti ọjọ́ kẹjọ ni ó ti di ìtẹ́wọ́gbà fún ọrẹ àfinásun sí Olúwa.